🎵

Eleduwa

Album: Eleduwa Durasi: 2:26

(M-M-Murderer)

Ijọ buruku lo n'ijọ titun

Baba, ṣo n gbọ oun aiye n sọ?

Eleduwa, ẹyin l'akọkọ ninu gbogbo nnkan

T'ẹ to d'aiye at'ọrun

And that why me I put You first

In everything I do

O ma ma ṣe, Ọlọrun mi, o pọ, o pọ ọ

Ibi t'ọn ni ki gbe-gbe ma gbe lo fi ṣabale

Ibi t'ọn ni ki tẹtẹ ma tẹ lo lọ ṣe vaca'

Ngba t'ọn tun wa sọrọ, wọn ni mi mọ ju Ọlọrun lọ

Baba, ṣo n gbọ oun aiye n sọ?

Ayun lọ, ayun bọ l'ọmọ ẹyẹ n rin

Nkan o ni tabala mi l'ẹsẹ lọla Ọlọrun

L'atoni lọ k'ọna mi ko la peregede

L'atoni lọ, ma gbe orilẹ yii ṣe oun re-re

Ẹyin to laiye ẹ gb'ohun mi ṣ'aṣẹ pa

I be ọmọ aiye, ẹ duro ti mi, ki n ma ṣe jabọ o

Ikoko la fi ṣe, e gbọdọ fọ o

T'aiye ma fọ igba ikoko mi l'ẹnu

Ay, ti n ba lu ṣe ni ko ma dun